Breaking News

Afcon 2019: Àwọn olólùfẹ́ Super Eagles fẹ́ kí Rohr tún wọn tò

Awọn ololufẹ ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles faraya lori idije to waye pẹluu Madagascar.
Awọn kan lara wọn gba pe akọnimọọgba wọn, Gernot Rohr n ṣe iṣẹ rẹ daada, nigba ti awọn kan sọ pe ko lo awọn agbabọọlu naa boṣeyẹ ko lo wọn.
Akọni ṣubú l'ójú ìjà, Madagascar fi 2-0 la Super Eagles mọ́lẹ̀
Ọkọ mi kò le f'ipá bá ẹnikẹ́ni lò pọ̀ láíláí - Modele Fatoyinbo
Bakan naa ni awọn kan di ẹbi ru awọn agbabọọlu naa. Ọpọ gbagbọ pe awọn kan lara wọn ti dagba ju fun idije naa.
Wọn gba Rohr ni imọran lati maa lo awọn agbabọọlu ‘kekeeke’.

No comments