Breaking News

Macky Sall di aare orile ede Senegal fun saa kejiMacky Sall di aare orile ede Senegal fun saa keji
Aare orile ede Naijiria Muhammed Buhari ti ki aare Macky Sall ku ori ire lati jawe olubori gege bi aare orile ede Senegal fun saa keji .
Aare Muhammadu Buhari tun ki awon omo orile ede Senegal fun aseyori eto idibo orile ede naa to lọ ni irọwọ ati irọsẹ.
O ni ; “Eto idibo to n waye nilẹ Afirika jẹ apẹẹrẹ rere pe eto ijoba tiwa-n-tiwa ti fẹsẹ mulẹ nilẹ  Afirika.”
Aare Buhari ni ireti pe ibasepo to wa laarin orile ede Senegal ati orile ede Naijiria yoo tubo fese mule sii paapaa julo ni awon eka bi i eto ọrọ- aje, isejọba ati eto iranwọ.

No comments